Ìṣe Àwọn Aposteli 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi ohun ìyanu hàn lókè ọ̀run,ati ohun abàmì lórí ilẹ̀ ayé;ẹ̀jẹ̀, ati iná, ìkùukùu ati èéfín.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:12-27