Ìṣe Àwọn Aposteli 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn yìí kò mutí yó bí ẹ ti rò, nítorí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ di agogo mẹsan-an òwúrọ̀ ni.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:11-20