Ìṣe Àwọn Aposteli 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru wá dìde dúró pẹlu àwọn aposteli mọkanla, ó sọ̀rọ̀ sókè, ó ní, “Ẹ̀yin ará, ẹ̀yin Juu, ati gbogbo ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerusalẹmu, ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yìí ye yín, kí ẹ fetí sí ọ̀rọ̀ mi.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:8-17