Ìṣe Àwọn Aposteli 19:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọ̀rẹ́ Paulu kan tí wọ́n jẹ́ ìjòyè ní agbègbè Esia ranṣẹ lọ bẹ̀ ẹ́ pé kí ó má yọjú sí ilé-ìṣeré nítorí gbogbo àwùjọ ti dàrú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:26-38