Ìṣe Àwọn Aposteli 19:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu fẹ́ wọ ibẹ̀ lọ bá àwọn èrò ṣugbọn àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu kò gbà fún un.

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:24-33