Ìṣe Àwọn Aposteli 19:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Pupọ ninu àwọn onigbagbọ ni wọ́n jẹ́wọ́ ohun tí wọ́n ti ṣe, tí wọ́n tún tú àṣírí idán tí wọn ń pa.

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:11-27