Ìṣe Àwọn Aposteli 19:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn Juu ati àwọn Giriki tí ó ń gbé Efesu ni wọ́n gbọ́ nípa ọ̀rọ̀ yìí. Ẹ̀rù ba gbogbo wọn; wọ́n sì gbé orúkọ Jesu Oluwa ga.

Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:11-25