Ìṣe Àwọn Aposteli 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dúró níbẹ̀ fún ìgbà díẹ̀. Ó bá tún kúrò, ó la agbègbè Galatia ati ti Firigia já, ó ń mú gbogbo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu lọ́kàn le.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:22-28