Ìṣe Àwọn Aposteli 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó gúnlẹ̀ ní Kesaria, ó lọ kí ìjọ ní Jerusalẹmu. Lẹ́yìn náà ó lọ sí Antioku.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:20-28