Ìṣe Àwọn Aposteli 17:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Jasoni sì ti gbà wọ́n sílé. Gbogbo wọn ń ṣe ohun tí ó lòdì sí àṣẹ Kesari. Wọ́n ní: ọba mìíràn wà, ìyẹn ni Jesu!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:1-8