Ìṣe Àwọn Aposteli 17:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọn kò rí wọn, wọ́n fa Jasoni ati díẹ̀ ninu àwọn onigbagbọ lọ siwaju àwọn aláṣẹ ìlú. Wọ́n ń kígbe pé, “Àwọn tí wọn ń da gbogbo ayé rú nìyí; wọ́n ti dé ìhín náà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:4-12