Ìṣe Àwọn Aposteli 17:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ti fojú fo àkókò tí eniyan kò ní ìmọ̀ dá. Ṣugbọn ní àkókò yìí, ó pàṣẹ fún gbogbo eniyan ní ibi gbogbo láti ronupiwada.

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:24-33