Ìṣe Àwọn Aposteli 17:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹnìkan sọ níbìkan pé:‘Ninu rẹ̀ ni à ń gbé,tí à ń rìn kiri,tí a wà láàyè.’Àwọn kan ninu àwọn akéwì yín pàápàá ti sọ ohun tó jọ bẹ́ẹ̀; wọ́n ní,‘Ọmọ rẹ̀ ni a jẹ́.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:27-29