Ìṣe Àwọn Aposteli 17:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹsẹkẹsẹ ni àwọn onigbagbọ bá ṣe ètò fún Paulu láti lọ sí èbúté. Ṣugbọn Sila ati Timoti dúró ní Beria.

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:6-20