Ìṣe Àwọn Aposteli 17:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí àwọn Juu ní Tẹsalonika mọ̀ pé Paulu ti tún waasu ọ̀rọ̀ Ọlọrun ní Beria, wọ́n wá sibẹ láti ṣe màdàrú ati láti dá rúkèrúdò sílẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:7-23