Ìṣe Àwọn Aposteli 17:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kọjá ní Amfipoli ati Apolonia kí wọn tó dé Tẹsalonika. Ilé ìpàdé àwọn Juu kan wà níbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:1-4