Ìṣe Àwọn Aposteli 16:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n jáde kúrò lẹ́wọ̀n, wọ́n lọ sí ilé Lidia. Lẹ́yìn tí wọ́n rí àwọn onigbagbọ, tí wọ́n sì gbà wọ́n níyànjú, wọ́n kúrò níbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:33-40