Ìṣe Àwọn Aposteli 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n súnmọ́ Misia, wọ́n gbìyànjú láti lọ sí Bitinia. Ṣugbọn Ẹ̀mí Jesu kò gbà fún wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:2-8