Ìṣe Àwọn Aposteli 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gba ilẹ̀ Firigia ati Galatia kọjá. Ẹ̀mí Mímọ́ kò gbà wọ́n láàyè láti lọ waasu ọ̀rọ̀ Oluwa ní Esia.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:1-13