Ìṣe Àwọn Aposteli 16:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó ti gba irú àṣẹ báyìí, ó sọ wọ́n sinu àtìmọ́lé ti inú patapata, ó tún fi ààbà kan ẹsẹ̀ wọn mọ́ igi.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:15-34