Ìṣe Àwọn Aposteli 16:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n ti nà wọ́n dáradára, wọ́n bá sọ wọ́n sẹ́wọ̀n. Wọ́n pàṣẹ fún ẹni tí ó ń ṣọ́ àwọn ẹlẹ́wọ̀n pé kí ó ṣọ́ wọn dáradára.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:20-27