Ìṣe Àwọn Aposteli 15:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn tí a rán kúrò, wọ́n dé Antioku, wọ́n pe gbogbo ìjọ, wọ́n fún wọn ní ìwé náà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:29-36