Ìṣe Àwọn Aposteli 15:29 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ẹ má jẹ ẹran tí a fi rúbọ sí oriṣa; kí ẹ má jẹ ẹ̀jẹ̀; kí ẹ má jẹ ẹran tí a lọ́ lọ́rùn pa; kí ẹ má ṣe àgbèrè. Bí ẹ bá takété sí àwọn nǹkan wọnyi, yóo dára. Ó dìgbà o!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:27-33