Ìṣe Àwọn Aposteli 15:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí láti ìgbà àtijọ́ ni wọ́n ti ń ké òkìkí Mose láti ìlú dé ìlú tí wọn sì ń ka ìwé rẹ̀ ninu gbogbo ilé ìpàdé lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:11-27