Ìṣe Àwọn Aposteli 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Kàkà bẹ́ẹ̀ kí á kọ ìwé sí wọn pé kí wọ́n takété sí ohunkohun tí ó bá ti di àìmọ́ nítorí pé a ti fi rúbọ sí oriṣa; kí wọn má ṣe àgbèrè, kí wọn má jẹ ẹran tí a lọ́ lọ́rùn pa, kí wọn má sì jẹ ẹ̀jẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:10-21