Ìṣe Àwọn Aposteli 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin yìí fetí sílẹ̀ bí Paulu ti ń sọ̀rọ̀. Paulu wá tẹjú mọ́ ọn lára, ó rí i pé ó ní igbagbọ pé wọ́n lè mú òun lára dá.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:2-17