Ìṣe Àwọn Aposteli 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà ní ìjókòó ní Listira tí ó yarọ. Láti ìgbà tí wọ́n ti bí i ni ó ti yarọ, kò fi ẹsẹ̀ rẹ̀ rìn rí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:5-18