Ìṣe Àwọn Aposteli 14:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹ kò ṣàì fi àmì ara rẹ̀ hàn: ó ń ṣe iṣẹ́ rere, ó ń rọ òjò fun yín láti ọ̀run, ó ń mú èso jáde lásìkò, ó ń fun yín ní oúnjẹ, ó tún ń mú inú yín dùn.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:14-25