Ìṣe Àwọn Aposteli 14:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìgbà ayé àwọn tí ó ti kọjá, ó jẹ́ kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè máa ṣe ohun tí ó wù wọ́n.

Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:6-23