Ìṣe Àwọn Aposteli 13:51 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn náà bá gbọn eruku ẹsẹ̀ wọn sílẹ̀ bí ẹ̀rí sí àwọn ará ìlú náà, wọ́n bá lọ sí Ikoniomu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:45-52