Ìṣe Àwọn Aposteli 13:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn Juu rú àwọn gbajúmọ̀ obinrin olùfọkànsìn sókè, ati àwọn eniyan pataki-pataki ní ìlú, ni wọ́n bá ń ṣe inúnibíni sí Paulu ati Banaba. Wọ́n lé wọn jáde kúrò ní agbègbè wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:40-52