Ìṣe Àwọn Aposteli 13:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí wọ́n ti gbààwẹ̀, tí wọ́n sì gbadura, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn lórí, wọ́n sì ní kí wọ́n máa lọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:1-5