Ìṣe Àwọn Aposteli 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti jọ ń sin Oluwa, tí wọ́n ń gbààwẹ̀, Ẹ̀mí Mímọ́ sọ fún wọn pé, “Ẹ ya Banaba ati Saulu sọ́tọ̀ fún mi, fún iṣẹ́ pataki kan tí mo ti pè wọ́n fún.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:1-12