Ìṣe Àwọn Aposteli 13:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Jesu tó yọjú, Johanu ti ń waasu fún gbogbo àwọn eniyan Israẹli pé kí wọ́n ṣe ìrìbọmi bí àmì pé wọ́n ronupiwada.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:14-29