Ìṣe Àwọn Aposteli 13:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti inú ìran rẹ̀ ni Ọlọrun ti gbé Jesu dìde bí Olùgbàlà fún Israẹli gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìlérí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:17-26