Ìṣe Àwọn Aposteli 13:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun àwọn eniyan yìí, eniyan Israẹli, yan àwọn baba wa. Nígbà tí wọn ń gbé ilẹ̀ Ijipti bí àlejò, Ọlọrun sọ wọ́n di eniyan ńlá. Ó fi agbára ńlá rẹ̀ hàn nígbà tí ó mú wọn jáde kúrò ní Ijipti.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:7-18