Ìṣe Àwọn Aposteli 13:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni Paulu bá dìde, ó gbé ọwọ́ sókè, ó ní:“Ẹ̀yin ọmọ Israẹli ati ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sin Ọlọrun wa, ẹ fetí sílẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:6-17