Ìṣe Àwọn Aposteli 12:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ Ọlọrun bẹ̀rẹ̀ sí fìdí múlẹ̀ sí i, ó sì túbọ̀ ń tàn káàkiri.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:16-25