Ìṣe Àwọn Aposteli 12:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹsẹkẹsẹ angẹli Oluwa bá lù ú pa, nítorí kò fi ògo fún Ọlọrun. Ni ìdin bá jẹ ẹ́ pa.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:13-25