Ìṣe Àwọn Aposteli 11:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Kristi bá pinnu pé olukuluku àwọn yóo sa gbogbo agbára rẹ̀ láti fi nǹkan ranṣẹ sí àwọn onigbagbọ tí ó ń gbé Judia.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:25-30