Ìṣe Àwọn Aposteli 11:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu wọn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Agabu bá dìde. Ẹ̀mí gbé e láti sọ pé ìyàn ńlá yóo mú ní gbogbo ayé. (Èyí ṣẹlẹ̀ ní ayé ọba Kilaudiu.)

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:21-30