Ìṣe Àwọn Aposteli 10:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹsẹkẹsẹ ni mo bá ranṣẹ sí ọ. O ṣeun tí o wá. Nisinsinyii gbogbo wa wà níwájú Ọlọrun láti gbọ́ ohun gbogbo tí Oluwa ti pa láṣẹ fún ọ láti sọ.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:26-42