Ìṣe Àwọn Aposteli 10:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ranṣẹ lọ sí Jọpa, kí o lọ pe Simoni tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Peteru wá. Ó dé sílé Simoni tí ń ṣe òwò awọ, létí òkun.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:27-39