Ìṣe Àwọn Aposteli 10:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó ti ń bá a sọ̀rọ̀, bẹ́ẹ̀ ni ó bá a wọlé. Ó rí ọ̀pọ̀ eniyan tí ó ti péjọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:20-37