Ìṣe Àwọn Aposteli 10:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Peteru fà á dìde, ó ní, “Dìde! Eniyan ni èmi náà.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:17-27