Ìṣe Àwọn Aposteli 10:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji tí wọ́n gbéra ní Jọpa ni wọ́n dé Kesaria. Kọniliu ti ń retí wọn. Ó ti pe àwọn ẹbí ati àwọn tí ó jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀ tímọ́tímọ́ jọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:23-31