Ìṣe Àwọn Aposteli 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹranko ẹlẹ́sẹ̀ mẹrin ati oríṣìíríṣìí ẹranko tí ó ń fi àyà fà, ati ẹyẹ ojú ọ̀run ni ó wà ninu rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:10-14