Ìṣe Àwọn Aposteli 10:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rí ọ̀run tí ó pínyà, tí nǹkankan bí aṣọ tí ó fẹ̀, tí ó ní igun mẹrin, ń bọ̀ wálẹ̀, títí ó fi dé ilẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:10-14