Hosia 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ pada sọ́dọ̀ OLUWA, kí ẹ sọ pé, “Mú ẹ̀ṣẹ̀ wa kúrò, gba ohun tí ó dára a óo sì máa yìn ọ́ lógo.

Hosia 14

Hosia 14:1-5