Hosia 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ pada tọ OLUWA Ọlọrun yín lọ, ẹ̀yin ọmọ Israẹli, nítorí pé ẹ ti kọsẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín.

Hosia 14

Hosia 14:1-7